
He would ask with rage of fire in his mouth
Who is Okoro?
If you asked Amadioha to go save Igbos in Kano
He would ask if it’s a quarters in Nnewi
If you called on the soul of Usman Dan-Fodio
To help the Hausa-Fulanis living in Lagos
He would say ‘that is a nation too far from Sokoto’
Thank goodness for Lugard
Who has brought us close as a family
Nigerians……let us live in unity and not unionism
Bí a bá bẹ Ṣàngó kí ó súre fún Okoro
Yóò bèrè pẹlú iná lẹnu
‘tani Okoro’
Bí a bá bẹ ‘Amadíọà’
Kí o lọ gba àwọn ọmọ Ìgbò ni ìlúu Kánò
Yóò bèrè bóyá agbolé ni ní ìlúu ‘Nnewi’
Bí a bá períi ẹlẹdáa Ùsmánù Dan-Fódíò
Kí o lọ sàánúu àwọn ẹya Awúsá àti Fúlàní
Tí n gbé ní ìlú Èkó
Yóò wípé orílẹ èdè ọwún jì sí ìlúù Sókótó
A dúpẹ lọwọọ orí fún Lùgáàdì
Tí ó fà wá mọra gẹgẹ bíi ẹbí
Ẹyin ọmọ Nàìjíríà……..Ẹ jẹ kí a gbé pẹlú ìsọ kan
Kí a má ṣe gbé pẹlúu ìmọ ẹyà m’ẹyà
Written by: Albert Seraphin
Edited by: Kukogho Iruesiri Samson
I like this – highly motivating, challenging and indigenous. I see a better Niyi Osundare and Femi Osofisan. Kukogho, keep it up!
Thank you